Home / Àṣà Oòduà / Alao Akala, Funke Adesiyan, Teslim Folarin àti àwon míràn ní won fi egbé alásìá tí a mò sí PDP sílè lo sí egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC.

Alao Akala, Funke Adesiyan, Teslim Folarin àti àwon míràn ní won fi egbé alásìá tí a mò sí PDP sílè lo sí egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC.

Baba ìsàlé egbé APC tí a mò sí asíwájú Bola Ahmed Tinubu, Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí ògbéni Rauf Aregbesola, Gómìnà ìpínlè Ondo, tí a mò sí Rotimi Akeredolu ní ìlú Ibadan ti fi tòwòtòwò gba olóyè Alao Akala, òsèré Funke Adesiyan, Teslim Folarin àti àwon míràn láti inú egbé PDP sí egbé APC.

About Admin Manager

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?