Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 12)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Àwon omo egbé APC ti Gúúsù Oyo ti jóòkó ìgbìmò – Abiola Ajimobi lo kí Alaafin Oyo.

Gómìnà ìpínlè Oyo , Abiola Ajimobi , tí ó ti fi okàn àwon omo egbé APC ti ìpínlè Oyo lókàn balè wípé omo egbé àwon ló ma wolé ní ibi ìdìbò tí ó n bò lónà ní odún 2019, àti ...

Read More »

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún. Olùsó Daniel Udoh, tí ó dá ilé ìjosìn “Agbejórò ni jésù” sílè ni owó sìkún ìjoba ti tè ní Akapabuyo, ìpínlè Cross river látàrí ...

Read More »

Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.

Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC. Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Ogbeni Rauf Aregbesola ti gun orí ténté okò láti polongo egbé won, egbé oní ìgbálè tí a mò sí ...

Read More »

Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a mò sí Tai solarin University of Education, ní ìpínlè Ogun.

Fídíò àti àwòrán àwon òdóbìnrin méjì tí ó ñ jà látàrí òrékúnrin kan ni ó ti gbalè kan . Akékòó ni àwon arábìnrin méjì yí àti wípé akékòó ilé-èkó ifáfitì ti Tai Solarin University Of Education ni won, ìpínlè Ogun, ...

Read More »

Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.

Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.  Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí ...

Read More »

Akékòó ilé-èkó gíga tí a mò sí Polytechnic ti ìlú Ede ní ìpínlè Osun ni àwon ará ìlú ti lù pa .

Ní àná ni akékòó ilé-èkó ti poly Ede fi okò pa ènìyàn bíi márùn-ún tí àwon omo tí ó sèsè fé wo ilé-èkó náà pélù okò rè. Bí ó tilè jé wípé, àwon ojú tí ó wà níbè náà so ...

Read More »

Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí fi owó rè ra èro ìbánisòrò ní ìpínlè Edo.

Owó àwon agbófinrín ti te arábìnrin kan ní ìpínlè Edo tí ó jé ìyá omo méjì , Miracle Johnson, fún títa omo rè omo òsè méfà tí ó sì di owó náà ra èro ìbánisòrò fún ara rè. Gégé bí ...

Read More »

Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn.

Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn. Ìyàlénu ñlá gbáà ni ayeye Àádòrún ojó-ìbí olúbàdàn ti ilè ìbàdàn tí a mò sí Oba Saliu Akanmu Adetunji ní ojó Àìkú. Gómìnà ìjoba ìpínlè Oyo Abiola Ajimobi ...

Read More »

Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà .

Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà . Sineto Musiliu Obanikoro tí ó jé adarí àwon olúdábòòbò ti orílè èdè Nìjíríà télè ti lo kí baba wa Oònirìsà tí a mò si àrólé odùduwà ní ìlú ilé-ifè ní ojó mélòó ...

Read More »

Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan lára àwon omo ilé BBNaija télè kú.

Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan lára àwon omo ilé BBNaija télè kú. Ará ilé àti lára àwon tí ó figa gbága ní BBNaija rí ni Bisola Aiyeola ...

Read More »