Hummmmmm ohun ta nfe la ndaso bo koseni tio mope irun ori poju irun ibikan lo woo orewa Nje o mope ohun taba gbe pamo ni I niyi? Moraso ogun mofi han eyan ogbon hummmmmm. gbomi dada Bisu eni bata ...
Read More »Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se!
A ku imura! Awo Alaseye! Isese o, o ti d’ogererere! Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se! Aase! K – Awodiran Agboola IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »Oruko kan fu foto yi ?
Oruko kan fu awon arakurin yii ?
Read More »Aja To Rele Ekun To Bo..
Aja ti o ba rele ekun ti o si pada lai f’arapa ti iru aja be o si le gbegba ope olowo aja be ni yoo fi se ounje ajesun laipe ojo. KABIYESI ILU MOYE ni a o ba maa ...
Read More »Oriki Ibeji
Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, ...
Read More »Odu Ifa Owonrin Tutu/ Oturupon
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio gbo adura wa o yio si bawa tu ile aye to ...
Read More »“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo….
“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo Wun ó bí’mo lé’mo n tó máalo Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo Bí Wón n n’íre lórun èmi ò mò Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo I will have enough ...
Read More »Egbo talo daran egbaafa ninu awon mejeji ?
Alabahun (ijapa) lo re ile ana re oni ohun le so epa mefa di egbaafa ki odun to yipo, alabahun gbin epa tan ikun de’be o wu epa je ni ijapa ba ni ikun ti daran egbaafa. Ibeere talo daran ...
Read More »Ogulutu Oro Toni – 09.08.2016
Hummmmmm onilari koseda tomola #woo_orewa Bo ba ndara fun o loni mase fi omolakeji re se yeye Mofe koranti pe kise agbara re ni ipo towa loni #gbomi_dada Iyanju lagbe ngba obami oke lo nmusu(yam) ta, bi agbara ba nbe ...
Read More »