Hummmmmm mase afarawe tori ohunti Taiye se tomuje ,kehinde lese koyi lowo.. Beere lowo orire kotolo Pate nibi Oja gbe nta Tori ohun gbogbo lowo ori ni ooo ooo….ire oooo King Ogulutu Oro
Read More »Ibeere Toni
Nje oda ki Ololufe Meji jo so bi won se gbe igbe aiye won kiwon to pade arawon paapa julo obinrin????
Read More »Itunmo Ala wipe Olopa mu yin.
Bio Bala alawipe loju orun olopa mue waa bo ninu ewu tio koju dae sungbon ti olopa ba mue tio fi handcuff sie lowo Oranla Kan nbo wa fune AFOWOFA arare ni yio si da oran naa sie Lorun kio ...
Read More »Itunmo: Bi e ba Lala wipe loju e’n sa ewa
Bi e ba lala wipe loju orun e’n sa ewa loju orun tabi e won ewa loju orun oore ibukun lopo lopo lati odo olorun oba ni ona owo lanla yio si Kano kio yara tete mura si adua ki olorun ...
Read More »Itunmo Ala wipe e ri obo loju orun
Bi o bala ala wipe loju orun wipe e ri awon obo (monkey) meji loju orun tiwon tele ara won alayi dara pupo olorun oba yio seo loore male gbagbe orore yio dayo ona owo yio la fune beesini bio ...
Read More »Omo Olojo Ibi toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Olori Aina Orosun ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu ...
Read More »Se Etuntigbo ?
Pekini ? ohunareoooooooo
Read More »Kilode ti iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo?
ojulu ni otito, ao gbo iru eleyi ri a fi d’eru ba oloro ni sugbon eleyi ko mi ni omi-inu kilo se alfa abdul-lateef titilope ifa-iwa(itakure) ki lo de ti iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo? aaaaaaa olohun-oba aseyi ...
Read More »Ifa naa ki bayi wipe
| | | | | | | | | | | | | YORUBA VERSION: Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi oni, emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa OKANRAN IRORUN ...
Read More »Awada Kerikeri
Ebi de, ebi mama de ooo nibo wonti nta oka nile yi Ebami wabo wa oo
Read More »