Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú Adeyẹmi, tó sì já mọ lọ́wọ́. Fẹ́mi Akínṣọlá Ọlayiwọla Adeyẹmi Kẹta, ti pé ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gọ́rín lókè eèpẹ̀ bẹ́ẹ́ ló ti lo ọdún méjìdínláàdọ́ta lórí ìtẹ́ àwọn baba ńlá rẹ̀. Òjò ti ń pa ...
Read More »Àsírí Òkété
ÒKÉTÉ.___Òkété jẹ́ ọ̀kan nínú ẹranko abàmì tó lágbára púpọ̀. A sì máa gbé nínú ihò. ELÉDÙMARÈ fún-un ní àṣẹ púpọ̀.Òkété kìí fi ọwọ́ tàbí ẹṣẹ̀ gbẹ́ ihò, ÌRÙ ni òkété maá n fií gbẹ́ ihò, fún ìdí èyí, ẹ ò ...
Read More »Bàbà wá Lérè paimo pé ọgọ́rin ọdún lónìí (80)
Ẹ jẹ ka jọ gbadura fun Ẹda Onile-ọla pe bi wọn ṣe ṣe tọdun yii ni wọn yoo ṣe tẹẹmi-in towo-tọmọ, ninu ilera pipe ati aiku ti i ṣe baalẹ ọrọ.
Read More »Àwon òrìsà tí e kò mò (sùgbón tí ó ye kí á mò) {Some Orisa you probably don’t know (But you have to)}
Òrìsà Bayani. Òrìsà alágbára yí ni òrìsà omodé tí a bí pèlú dàda . Ó dára kí a ma bo òrìsà yí kí á sì ma bèèrè fún ìdábòbò, kí á b’orí òtá àti gbogbo ire ilé ayé. Gbogbo ...
Read More »Ori Eni Lawure Eni O…
Ori Eni Lawure Eni O Ori Eni Lawure Eni Mo ji lowuro mo dewo mori O Ori Eni Lawure Eni… Ki Ori wa ma sowa nu ooo… Ase Ire O! Translation One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell(2ce) I woke ...
Read More »Gbenga Ojoyido n jaye bi oba Lamidi niluu Amerika
Won ti so mi lenu, idi ni yii ti mo fi pinnu lati dake. Won ti fabuku kan mi, idi ni yii ti mo fi senu mi ni deede sibi. Awon kan tile leri wi pe maa kandin ninu iyo, ...
Read More »