Kí ojú má ríbi, gbogbo ara lòògùn rẹ̀, èyí ló mú kí Gómìnà ipinlẹ Ọyọ, Ṣèyí Mákindé sáré tètè gba ìlú Abẹokuta lọ, láti lọ ṣèpàdé pọ̀ pẹ̀lú Olóyè Olusẹgun Ọbasanjọ.
Read More »Ìdí tí nó̩ḿbà ìdánimò̩ kò fi jé̩ dandan mó̩ – Àjo̩ JAMB
Ẹ kò nílò nọńbà ìdánimọ̀ NIN fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020… Àjọ JAMB Fẹ́mi Akínṣọlá Ni báyìí Àjọ tó ń rí sí ìdánwò àṣewọlé ilé ẹ̀kọ́ gíga JAMB tí kó àfàró nípa lílo nọ́mbà ìdánimọ̀ “NIN” fún ìdánwò àṣewọlé ọdún ...
Read More »Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira
Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn aláṣẹ tọ́rọ̀ kan lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti kó àgádágodo sílẹ̀kùn ilé ọmọ aláìóbìí kan tí kò ní wè é òfin ní ìpínlẹ̀ Kaduna, tí wọ́n sì tú ọmọdé ...
Read More »Naira Marley ń rìn ní bèbè ẹ̀wọ̀n lọ́dún 2020 bí kò bá fara hàn lórí ẹ̀sùn ìjọ́kọ̀gbé – Ilé ẹjọ́
Naira Marley ń rìn ní bèbè ẹ̀wọ̀n lọ́dún 2020 bí kò bá fara hàn lórí ẹ̀sùn ìjọ́kọ̀gbé…..Ilé ẹjọ́ Àdúrà ká má rẹ́jọ́ loníkálukú ń gbà,kí èṣù ó sì má yá wa lò.Ṣùgbọ́n bí nǹkan ṣe ń lọ yìí fún Naira ...
Read More »Ohun t’ọ́kùnrin ń ṣe l’Ekiti, obìnrin lè ṣe é. Àjọ̀dún Àṣà ìbílẹ̀ lékìtì
Àṣà àti ìṣe wà nínú n tíí ṣàfíhàn èèyàn bí ọmọ ọkọ tàbí ọmọ ìdàkejì n ló díá fún bí onírúurú ohun tẹ́ ẹ̀ tilẹ̀ mọ pé ó wà láyé yìí se dohun àfojúrí níbi ayẹyẹ àjọ̀dún àṣà ọdún yìí ní ipinlẹ Èkìtì, .
Read More »Mu pàrágá wakọ̀ l’Ọyọ, kóo kó sí páńpé̩ ìjọba
Omi tuntun ti rú, ẹja tuntun ti wọ ọ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Awakọ̀ mẹẹdọgbọn ni ọwọ́ òfin ti tẹ̀ nìpínlẹ̀ náà lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ń mutÍ nígbà tí wọ́n tún ń wa ọkọ̀.
Read More »Olè yabo báńkì: O fowó náà so̩dún Kérésì fáwọn èrò
Olè yabo báńkì. O fowó náà so̩dún Kérésì fáwọn èrò Bí ayé bá ń lọ sópin, àràǹbarà ìran lojú yóó máa rí. À bí kín ní ká tí pèyí sí pẹ̀lú bí arákùnrin òyìnbó onírungbọ̀ kan ṣe dédé yabo ilé ...
Read More »Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì
http://iroyinowuro.com.ng/2019/12/24/ogba-ewon-ni-pasito-sotitobire-yoo-ti-%e1%b9%a3e-keresi/ Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ondo ti gbé Pásítọ̀ Alfa Babatunde tíí ṣe olùdásílẹ̀ Ìjọ Sòtítọbírẹ ní Ondo lọ Ilé ẹjọ́ léyìí tí ìwòye sì tún ń ṣàfihàn rẹ̀ báyìí pé Wòlíì náà ...
Read More »Ìròyìn Òwúrò̩ t’ò̩s̩è̩ yí
Mo ti pàṣẹ fún àjọ DSS láti tẹ̀lé àṣẹ ilé ẹjọ́….Abubakar Malami
Ìjọba àpapọ̀ ti pàṣẹ pé kí wọ́n tú olùbádámọràn lóri ètò ààbò Sambo Dasuki àti agbétẹrù Revolution Now Omoyele Sowore silẹ̀ nínú àhámọ́.
Read More »