IROYIN OWURO ose yii ti jade ooo
Iru iku wo lo pa Sikiru Ayinde Barry Wonder? Inu iwe Iroyin Owuro ose yii ni e o ti ri. E gbiyanju ke e bere lowo fendo yin. Ogorun naira pere ni.
Read More »
Iru iku wo lo pa Sikiru Ayinde Barry Wonder? Inu iwe Iroyin Owuro ose yii ni e o ti ri. E gbiyanju ke e bere lowo fendo yin. Ogorun naira pere ni.
Read More »Aimoye awon omo wewe ni won pejo si bi ayeye odun keresimesi ati babakeresi ti ile ise redio Fesh FM ti Yinka Ayefele eleyii to waye ni Music House, ile orin Ayefele, to kale siluu Ibadan. Asekagba naa lo waye ...
Read More »Okan pataki ninu awon oloye egbe APC nipinle Ondo, Niran Sule-Akinsuyi, ti so yanya wi pe niseju Gomina Olusegun Mimiko ni egbe oselu PDP ipinle naa yoo fi di ohun a-fi-seyin teegun fiso. Oro yii lo n so nigba to ...
Read More »*Omo oloogbe Abubakar Audu n be leyin re. *Kilode ti Tinubu ko da soro naa? Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Lojo Aje to koja yii ni rugudu ti n lo lagbo oselu nipinle Kogi tun bureke si i nigba ti Ogbeni ...
Read More »Alaga egbe oselu APC, oloye John Odigie-Oyegun ti fi da awon omo Naijiria loju wi pe, kosi ipadaseyin ninu yiyo owo iranwo ori epo robi. Oyegun lo n soro yii nigba ti n gbalejo awon iko kan lati inu egbe ...
Read More »Iroyin Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Gomina Rauf Aregbesola tipinle Osun ti lo si ileewe girama, Olufi Middle School to kale si Gbongan ni Ijoba Ibile Ayedaade to wa nipinle naa. Nibi ayeye ti won ti n si ileewe naa ni ...
Read More »Ogbeni Amaju Pinnick to je aare ajo ti n risi ere boolu alafesegba, Nigeria Football Federation, ti fesi lati tako awon aheso kan ti n lo nigboro wi pe, ajo NFF n se bisineesi tita agbaboolu soke okun. O ni ...
Read More »Komisanna awon olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Abdulmajid Ali ti kede wi pe,ile ise olopaa ipinle Ogun ti wa ni imurasile lati gbogun ti iwa idaran to seese ko suyo lasiko poposinsin odun taa wa yii. Ninu oro Ogbeni Abdulmajid, eleyii ...
Read More »E ni lati fi eti ara yin gbo ohun ti Omooba Yomi Tejuosho so nipa Oloye Gani Adams. Eniyan ti a n ri lokeere, aimoye nnkan ni e ko mo nipa eni naa.rara.
Read More »Okan ninu awon asofin, Honourable Essien Ekpenyong Ayi (PDP) lati ipinle Cross River n sun ni akoko ti Aare Buhari n ka iwe eto isuna odun 2016 niwaju ile igbimo asofin Abuja.
Read More »