INEC ti kede Yahaya Bello gege bi gomina tilu dibo yan nipinle Kogi
Ajo INEC ti kede Alh. Yahaya Bello gege bi gomina tuntun tilu sese dibo yan. Ninu eto idibo eleyii ti asekagba re waye lana ni Bello lati inu egbe onigbale, APC, ti ni apapo ibo 247,752. Nigba ti PDP ni ...
Read More »