Kini ijoba n se nipa awon ti n se ayederu?
Orisun iwe Iroyin Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon iroyin bayii, a kan maa n gbo ...
Read More »
Orisun iwe Iroyin Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon iroyin bayii, a kan maa n gbo ...
Read More »Awon eniyan oba ni Osupa ti mura tan lati gbe awo orin re tuntun jade. E le ka iroyin naa NIBI. Eniwee, mo sakiyesi wi pe awon aso okeere maa n mu oju osupa dabi odomode nigba ti awon aso ibile ...
Read More »Oni fila yii
Read More »1. Ehin le yingin tabi ki die kan lara ehin wa: Nigba mi-in ti a ba n gbiyanju lati fi ehin ge eekanna wa, ehin wa le lura won lojiji, eleyii si le fa ki ehin yingin legbe kan tabi ...
Read More »O ku die ko je gomina niku mu lo. Igba ti okiki re bere si ni i kan, lo wole sun. Ojo ti idile re i ba fo fayo, ni won bo sinu ibanuje nla. Ile aye asan, ile aye ...
Read More »Omodebirin yii ni okan ninu awon iyawo tuntun ti Abubarka Audu ko sile to fi n sararindin nigba aye re. Gege bi ohun ti Olayemi Oniroyin gbo, ojo ori omobirin naa ko le ju bi odun mejidinlogun (18) si ogun ...
Read More »Won sin Abubakar Audu lonii ni ilu re, Ogbonicha to wa ni ijoba ibile Ofu ni ipinle Kogi.
Read More »Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, wa lara awon alejo pataki ti won peju sibi ayeye odun marunlelogbon (35) ti won ti da ile ise SilverBird sile. Minisita fun eto iroyin, Oloye Lai Mohammed naa wa nibe lati soju ...
Read More »Laipe yii ni Feyikemi Niyi-Olayinka, okan ninu awon sorosoro ori telifisan, dagbere irin-ajo re siluu London. Aworan re ni yii pelu okan lara awon osere tiata Nollywood, Sola Sobowale, niluu London. Lara awon fiimu olokiki ti Sola Sobowale se ni fiimu Lagidigba, ...
Read More »Titi aye ni olowo yoo ma sore olowo. Gbajumo yoo ma sore gbajumo nigba ti awon olosi naa yoo ma ba ara won se ninu asosiesan awon mekunnu. Aisha Buhari, aya aare ile Naijiria ti lo ki Oloye agba egbe ...
Read More »