Ifá náà ki bayi wípé: Adaku Adaoku
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi, aku ise ana o, a si tun ku imura toni, gegebi a se mo wípé oni je ojó isegun, ogun buburu yio se ninu igbesi ayé wa loni o Àse. E jeki a fi ...
Read More »
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi, aku ise ana o, a si tun ku imura toni, gegebi a se mo wípé oni je ojó isegun, ogun buburu yio se ninu igbesi ayé wa loni o Àse. E jeki a fi ...
Read More »Bàbá bàbá kan tí ó jé bàbá orílè èdè Nàìjíríà àti ìyá ìyá ni won se ayeye ojó ìbí fún nígbà tí won pé ogóòrún àti márùndínlógóòrún. Gégé bí olùsòrò kan lórí èro ayélujára se so àti olùsòrò gbogbogbò ...
Read More »Àwon Alábagbélé àti olùgbépò télè ti big brother Naija, àwon tí a mò sí Vandora, Princess, Dee one , Bitto àti àwon tí won lé kúrò Khloe àti k Brule se àbèwò sí ìkan lára àwon ilé-isé tí ...
Read More »Anamoyayà (civil defence officer) ni àwon Fulani darandaran pa ní ìjoba ìbílè Guma ní ìpìnlè Benue ni won ti sín pèlú òpòlopò omijé. Àwon emèwà rè ti sin ín tomijé tomijé.
Read More »Arákúnrin tí ó jé ígbò yí ti se ayeye ìgbéyàwó ìbílè alárinrin, tí ó sì ti fé ìyàwó rè òyìnbó n’ísu l’ókà. Gégé bí ìgbéyàwó náà se wáyé ní ojó ketàdínlógún osù kejì odún yí (17/2/2018) , a rí àwòrán ...
Read More »Aàrẹ Ọ̀nà Kakanfo, Ọ̀túnba Gàní Adams ti wọn ṣe ìwúyè fún ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, oṣù kini, ọjọ́ kẹtàlá ọdún Ẹgbàáléméjìdínlógún fi ẹ̀dùn ọkàn hàn nipa bi àṣà àti ìṣe Yoruba ti fẹ́ parẹ́. Nigba ìwúyè, Ọ̀túnba Gàní Adams ṣe àlàyé ...
Read More »Ekaaro eyin eniyan mi, aku ise ana o, a sin tun ku imura toni, mose ni iwure laaro yi wipe Eledumare ninu aanu re koni jeki ire oni yi fiwa sile Àse. Idanileko mi toni da lori orí wa, opolopo ...
Read More »Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, bi a se njade lo loni Eledumare ninu aanu re yio jeki ire oni yi je tiwa Àse. Laaro yi mofe soro soki nipa èsù òdàrà, o seni laanu lode ...
Read More »Esè la fí ñ rìnnà Olà Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo… Asáré pajé Arìngbèrè polà Òhun ewà ní wón jó n wòlú Adífáfún Ògbìngbìn kan Ògbìngbìn ...
Read More »