E wo ejò tí aládùúgbò mi pa, e jò wó kíni orúko rè.
Aládùúgbò mi ló pa ejò nlá yí ní kùtùkùtù òwúrò àná … Oúnje ti se.
Read More »
Aládùúgbò mi ló pa ejò nlá yí ní kùtùkùtù òwúrò àná … Oúnje ti se.
Read More »Onísòwò aso àti olù gbé eré jáde, Laura Ikeji gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí ó ya ni lénu yí.
Read More »Akoni òsèré , Obi Madubogwu tí ó kú ní ojó kejìdínló’gbòn osù kejo ( 28/8) nígbà tí ó jèrora ìtò súgà fún bí odún díè séyìn ni won ti sin sí ìlú rè ní Ogidi ìpínlè Anambra. Gbajúgbajà òsèré ...
Read More »Òrìsà ni olókun jé, a gbó wípé òun ni ó bí ajé, ó tún jé òrìsà orò àti ti ìsàlè òkun. Olókun ni ó n darí omi ó sì ní àse l’órí gbogbo ìsèdá inú omi . Olókun máa ...
Read More »E má jé kí èrù bà wá . Kíkùn lásán ni , àti wípé èjè iró ni ó wà níbè “.
Read More »Òsèrè orí ìtàgé, Tonto Dikeh gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí tí òun àti òré rè tímótímó , òsèré Halima Abubakar yà.
Read More »Àwòrán bàbá kan láti orílè èdè Nàíjíríà pèlú àwon omo rè obìnrin méfà tí ó rewà. Baba tí orí rè wú pín àwòrán àwon omo rè obìnrin méfà. Won rewà gan ni. Nse ni ó dàbi kí èmi náà ...
Read More »Ère tí ó bù áyà tí ó fi àsà wa hàn ní Ikorodu ni Gómìnà ìpínlè Èkó ti báwa sí lánàá.
Read More »Kí ló n selè báyìí? Se Davido sèsè n bò ni ? Obìnrin ehn ! E wo bí Davido se n wò bí eni tí ó n lo sí àjùlé òrun re . Òrò kan fun un e jò ...
Read More »Funke Akindele tí gbogbo ayé mò sí Jennifer tún yo ní àrà òtò níbi àwòrán yí…
Read More »