Nabila Fash pe àwon obìnrin níjà bí won bá le ya àwòrán làì kunjú bí ti tò òun.
Bí Nabila, ìyàwó olórin kan, Oritsefemi se pín àwòrán tí kò ti kunju tí ó so wípé òun yà léyìn ìdárayá ní òwúrò àná.
Read More »
Bí Nabila, ìyàwó olórin kan, Oritsefemi se pín àwòrán tí kò ti kunju tí ó so wípé òun yà léyìn ìdárayá ní òwúrò àná.
Read More »Gómìnà Anambra Willie Obiano náà dìbò fún ara rè ní Otuocha ward 1 unit 004.
Read More »Àwon òdó míràn gbádùn Nsala won, gégé bí won se pín sí orí èro ayélujára.
Read More »Adesua ti se tán láti se tán láti se ìgbéyàwó. Ìgbéyàwó rè ti è ti súmón etílé.
Read More »Omo egbé PDP tí ó n lo fún fún ipò níbi ìdìbò Anambra Oseloka Obaze níbi tí ó ti dìbò fún ara rè.
Read More »Wón so ìran adúláwò dí eranko, kódà isé tí eranko kò le jé ni won n fi won jé . Won n lo ìran adúláwò n’ílò Ku lò.
Read More »Kì í kú se wípé olórun d’àwa l’ájá béè kò dáwa l’éranko bí kò se wípé ó dáwa láláwò dúdú, ó sì dá àwon kan pupa. Sùgbón kò fi enìkan se erú enìkan.
Read More »Juliet Ibrahim ti wà nínú agbami ìfé, nse ni ó dàbí pé ó ti pàdé adé orí rè. Òsèré kan ní orílè èdè Nàíjíríà ti fi èhónú rè hàn sí afòròdárà (rapper) kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Iceberg ...
Read More »Àwòrán èyí kí ó tó di ojó ìgbéyàwó ti arákùnrin Igbo tí a mò sí Ofor, tí ó ti se tán láti fé aya àfésónà rè Witney tí ó jé Calabar ní ojó etì, ojó kejìdínlógún osù kokànlá odún yí ...
Read More »Igbékejì Gómìnà ìpínlè Imo , Omoba Eze Madumere àti aya tí ó sèsè fé, Omoba Chioma Rosemary Madumere kí omobìnrin káàbò léyìn osù méjì léyìn ìgbéyàwó, won ti bí omobìnrin. Igbékejì Gómìnà ni ó pín àwòrán yí tí ...
Read More »