Àwon òjògbón lòdì sí ìbára eni lòpò láì lo ìdábòbò.
Dókítà tí ó ń wo àìsàn tí ó je mó èyà ara omo bíbí (Gynecologist) Dr. Uche Ene, ti gba àwon òdó ní ìmòràn kí won yàgò fún ìbálòpò tí kò ní ìdábòbò kí won má ba kó Àtòsí (gonorrhea) ...
Read More »
Dókítà tí ó ń wo àìsàn tí ó je mó èyà ara omo bíbí (Gynecologist) Dr. Uche Ene, ti gba àwon òdó ní ìmòràn kí won yàgò fún ìbálòpò tí kò ní ìdábòbò kí won má ba kó Àtòsí (gonorrhea) ...
Read More »Ti o ko ogorun ebe. Ti o wa de ile ti n so fun gbogbo eniyan wipe Igba ebe loun ko loko … Eyin efi IRU eniyan be sile. Nigba ti o BA je ogorun otito tan. Funrare na Ni ...
Read More »(gbajugbaja osere oni theatre )
Read More »Ohun méje (7) tí ó jé èdùn okàn tí enikéni kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga. 1- ilé-èkó gíga ifáfitì wà fún mímo irú èèyàn tí o jé, lo àkókò àti ànfààní tí o bá ní ...
Read More »Ókéré jù àwon ènìyàn méèdógún (15) ni a gbó pé àwon agbésùmòmí Boko Haram pa nígbà tí won kolu ara won. Ìròyìn tí Orísun àwon figilanté gbé ni wípé òpò àwon ará ìlú ní won sì ń wá léyìn Ìsèlè ...
Read More »Gégé bí olùrànlówó oníròyìn ti ìjoba ìpínlè Sokoto, Imam Imam òsìsé ológun (army officer) M Maiwada àwòrán eni tí ó wà lókè tí ó sèsè di Balogun (captain) ni won yín ìbon pa ní ojú ogun pèlú àwon Boko Haram ...
Read More »Konmísónà tí ó ń mójú tó àyíká (commissioner of environment), tí a mò sí Hon. Barr John Nani àti àwon emèwà rè kolu tí won sì pa olúfà ńlá tí ó won òsùwòn tí ó tó mítà lónà mérin ó ...
Read More »Léyìn àrídájú tó ji-n-gí-ri, mo le f’owó s’òyà pé pé ilé-èkó Nwafor Orizu College of Education Nsugbe ti pàdánù tí ó pò . Arákùnrin Mr Osaji Charles, tí ó jé Mr NASELS télè (2013/2014 session), ni won yín ...
Read More »Láàrin ogún-l’ógbòn àwon akékòó tí ó tó 1,559,162 tí won jòkó fún ìdánwò àsekágbá ilé -èkó girama tí a mò sí waec ní odún 2017 tí ó jé wípé òpò ni a ti rí, tí ó sì dára … Akékòó ...
Read More »Àwon ajínigbé mérin, èyí tí won ti ń da ìpínlè Abia àti agbègbè rè láàmú. Won ti ń gbìyànjú àti parun tí àwon òtelèmúyé so mó Omoba Division ní ojó ketàdínlógún osù keje (19th July ,2017) ní Ovungwu, Isiala -Ngwa ...
Read More »