Ilé Tí Won Ń Kó Lówó Wó Ní Ilorin.
Èrù ti ń ba àwon òpòlopò ènìyàn bóyá àwon ènìyàn kú sí inú ilé tí won ń kó lówó ní òpópónà Stella, Tanke ,Ilorin ,ní ìjoba ìpínlè Kwara tí ó wó ní òsán yí. English version Continue after the page ...
Read More »
Èrù ti ń ba àwon òpòlopò ènìyàn bóyá àwon ènìyàn kú sí inú ilé tí won ń kó lówó ní òpópónà Stella, Tanke ,Ilorin ,ní ìjoba ìpínlè Kwara tí ó wó ní òsán yí. English version Continue after the page ...
Read More »–Tí ó sì dá àpá sí won l’ára. Nígbà tí a wà lénu síse àtakò àláfíà sí ilé ìjoba Makurdi lóòní láti jé kí ìjoba gbárùkù láti jé kí won f’owó sí owó ntanràn jíjeko (Anti grazing bill) sínú ...
Read More »Gbajúgbajà olórin, Kcee o ní ìràwò márùn-ùn. Nínú Orin tí ó ti se jé kí á rí àsírí rè gégé bí àsáájú tí ó kókó lo okò bògìnì “Rolls-Royce ní ilé-isé olórin ní orílè èdè Nàìjíríà. Òun ni ó ...
Read More »Ní ìsàlè yìí ni àwòrán sineto Obanikoro àti sineto Oluremi Tinubu àti àwon tó kùn. Ní ìpàdé kejilélógún (22nd) ní ibi ìpàdé àwon sinetò ní agbègbè èkó …. English Version after the page break
Read More »Gbajúgbajà olórin 2baba jé òkan lára àwon tí ó korin ní Glomega tour ní VI ní ìlú èkó. Ó tún wú àwon ònwòran lórí nígbà tí ó f’akoyo lórí ìtàgé. Ewo àwòrán bí ó se Ń dá won lárayá n’ísàlè.. ...
Read More »Òsèré Biodun Okeowo tí a mò sí Omobutty, ni àwon olólùfé rè ń sòrò sí látàrí àwòrán tí ó pín ní bi tí ó ti wo aso tí ó gbé èyà ara rè jáde… Continue after the page break for ...
Read More »Akékòó odún keta (300l) ti eka èkó pharmacy, Obafemi Awolowo University; pàdánù èmí rè Lánàá léyìn ìgbà tí ó rì sómi nínú odò-ìwè (swimming pool) ní hòtéèlì tí a mò sí Hilton. A mò ó sí Fatile Emmanuel. Ìsèlè yí ...
Read More »Ò n lo èro ayélujàra (facebook user) Ebere Amalaha tí ó ń jé ìyá ń dá gbé, múra bíi okùnrin láti se ayeye àjòdún baba tí ó wáyé ní ojó kejìdínlógún osù kefà (June 18). Pín àwòrán ara rè bí ...
Read More »Léyìn wíwá ènìyàn pàtàkì ní ìlú Kenya ,Vera Sidika pín àwòrán tí ó fi hàn wípé kò bá ti tún gbàgbé odómokùnrin míràn ní orílè èdè Nàìjíríà tí owó kún àpò rè. òrékùnrin àtijó rè dapadà fún un nípa pínpín ...
Read More »Nígbà tí won ti mu fún èsùn kan náà. Arákùnrin tí ó wà nínú àwòrán ní ìsàlè yìí tí ó yan isé okò jíjígbé láàyò ni owó sìkún àwon olóòpá bà ní Yenegoa, ní ìjoba ìpínlè Bayelsa fún ìgbà keta. ...
Read More »