Home / Test2page 91

Test2

Iwure Ojo Aje 3/10/2016

Ekaro oo se dara dara laji lowuro eni o gege bi emi na se ji oo toba ribee ejekia dupe lowo olodumare kiafi okan kan dupe lowo eleda wa ejekia bo si iwaju oke ipori wa pelu obi tabi eyi ...

Read More »

Olojo Ibi Toni

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Princess Oluwakemi Morenikeji Idowu ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re ...

Read More »

Iwure to Ori (for Good Luck)

Ka ji ni kutukutu Ka mu ohun ipin ko’pin d’Ifa fun Olomo-ajiba’re-pade Emi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pin Emi ni mo ba ire pade l’ola Translation To wake up early morning And give destiny its ...

Read More »

Odu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe..

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Eku ojo meta o, Ogun lakaye yio bawa segun awon ota wa yio si lana ire gbogbo funwa loni ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Irete Osa kubu irete Osa kebe, irete ...

Read More »

Ayeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo

Ododun larorogbo Ododun lari awusa Ododun lati mo obi lori ate Ododun ni sapo nruwe Ododun ni peregun yio Ododun leo ma bee ninu ola ati Alaafia Alekun ogbon Alekun Oye Alekun IMO Alekun emi gigun Alekun Alaafia Oju asa ...

Read More »

Ori mi segbe leyin mi ooo..

Ori eni lawure eni ni, Ori mi segbe leyin mi ooo. Ori a gbe wa o.Ase oo

Read More »

Odu Ifa Iwure Ti Aaro Yi Ki Bayi Wipe

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tu ku imura toni eledumare koni jeki won gberu ibanuje wa kawa mole loni o ase. Odu ifa iwure ti aaro yi ki bayi wipe: Oseka ori odi ...

Read More »

Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo

  Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose ...

Read More »

Ipade! Ipade! Ipade!

“Mo se ileri fun orisun mi Ti I se ile yoruba, Lati je omo yoruba atata nileloko, Ati lati je omo oko, Ti ki I f’owo osi Juwe ile baba re, Lati gbe ise, asa Ati ede yoruba laruge, Nibi ...

Read More »

Pari owe yii..

Bi ọdẹ ba ro iṣẹ, ro iya, boba pẹran ………..

Read More »