Pari owe yii..
Bi ọdẹ ba ro iṣẹ, ro iya, boba pẹran ………..
Read More »
Bi ọdẹ ba ro iṣẹ, ro iya, boba pẹran ………..
Read More »Hummmmmm ile eni lati nje ekute oni dodo, Morojo oko re feni kankan mo Tori Kosi bi tise o si oni kaluku naa nfaso bo tie ni wara o si loni, wara nbo lola Woo Orewa Kosokunrin tope nile aiye ...
Read More »Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a sanwa sire gbogbo o ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Òkan fìkìkìkì babalawo oladeji difa fun oladeji eyiti won nfojojumo njuwe re fun iku, won ni ...
Read More »Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Ido Alayo ti ose yi. ...
Read More »Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku aseku odun emi wa yoo se pupo re laye, layo ati ni alafia ara. Mo si ki awa ololufe eto yi, wi pe e ku ...
Read More »Owo idana o po ooo 5,000 pere ni oooooo
Read More »Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Ojó oni a san wa o ao ri tiwa se o ase. Gegebi awon opolopo eniyan se maa nsoro wipe “atewolabala ao meni to ko” lotito la ba ila latelewo wa sugbon imo ijinle ...
Read More »Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku aseku odun o emin wa yio se pupo re laye awon alaseku yio bawa se o, ako ni rogun inira o ase. Ifa iwure toni jade ninu odu ifa Ogundigara Ifa naa ki ...
Read More »