Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán Afárá(Bridge)tí ó já tí won sì ti kò sílè ní ìlú Ilorin .

Àwòrán Afárá(Bridge)tí ó já tí won sì ti kò sílè ní ìlú Ilorin .

      Afárá (Bridge ) yí ni òjò ti gbá dànù láti bí osù díè séyìn látàrí òjò nlá tí ó rò tí àwon ìjoba kò sì se nkankan si . ònà alágbàdo ni afárá yí wà . Nígbà tí mo dé Ilorin òná yí ni ó ye kí n gbà sugbòn tí mo padà lo gba ònà tí ó jì jù lo…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo