Home / Àṣà Oòduà / E ba wa dasi oro yii: Ninu ipo ati iya eni, e wo lo gaju?

E ba wa dasi oro yii: Ninu ipo ati iya eni, e wo lo gaju?

Leyin ti won fi Sanusi je Emir tilu Kano, oba. Ilu Kano si gba wi pe oosa ajiki bi iya ko si laye. Eleyii lo mu gomina banki agba ile yii nigba kan ri teriba niwaju yeye to bi i lomo.

Nje asa Yoruba tewogba iru ohun ti Sanusi se yii?
Nje Ooni tuntun le se iru re?
Ninu iya eni ati ipo oba, e wo lo gaju?

About oodua

One comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.