Home / Àṣà Oòduà / E wa wo bobo to fi tattoo ya Davido si aya re

E wa wo bobo to fi tattoo ya Davido si aya re


Davido pada pade bobo to fi tattoo ya aworan omo baba olowo si igbaaya re. Ebun ti Davido fun naa ni alakorun ti won fi goolu se. O si so fun bobo naa wi pe awon ti di abi kan naa.

About BalogunAdesina

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.

Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.  Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí kò torí owó, orò bàbá rè má sisé mó, tí ó je wípé takuntakun ni ó fí n sisé láti le di èèyàn ñlá àti èèyàn pàtàkì tí àlá rè sì ti wá sí ìmúse. Omo bàbá olówó ni gbogbo ...