Home / Àṣà Oòduà / Èèmò! Nígbà tí Gómìnà ìjòba ìpínlè Oyo wó ilé ìròyìn Yinka Ayefele ní ìlú Ibadan. Èyí kìí se àheso rárá, béè ní Gómìnà ìpínlè Oyo kò bá Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yinka Ayefele se eré rárá.

Èèmò! Nígbà tí Gómìnà ìjòba ìpínlè Oyo wó ilé ìròyìn Yinka Ayefele ní ìlú Ibadan. Èyí kìí se àheso rárá, béè ní Gómìnà ìpínlè Oyo kò bá Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yinka Ayefele se eré rárá.

Ní òwúrò ànà tí se ojó Àìkú ní ariwo ta ní ìlú Ibadan ní ìpínlè Oyo nígbà tí ijoba ìpínlè náà pàse kí won wó ilé-isé ìròyìn ti Yinka Ayefele tí a mò sí Fresh Fm tí ó wà ní òpópónà Challenge ní ìlú Ibadan.

Ilé-isé ìròyìn yí won ní ó won mílíónú lónà 800. Èyí kò da ní gbogbo ará ìlú ñ pariwo nítórí wípé Yinka ko le dìde rin.
Gégé bí a se gbó àwon omo orílè èdè Nìjíríà ti bèrè síní ran-án lówó tí òpò sì ti ñ dá owó fun.
Kí olúwa bá wa se é ní ilé oba tó jó ewà ló bùnkùn.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo