Home / Àṣà Oòduà / Iba Gani Adams pàdánù baba rè .

Iba Gani Adams pàdánù baba rè .

Baba Ààre Ona-kakanfo ti ilè Yorùbá tí a mò sí Iba Gani Adams ti lo.
Pa Lamidi Adams tí ó ta téru nípà ní ojó Àbáméta ní ilé ìwòsàn aládáni ní ìpínlè Eko, baba kú ní ìgbà tí won fé pé ogórin odún.
Nínú ìròyìn tí a gbó, a gbó wípé baba ní àwon oko agbèrò tí won dá ni, ní Oturkpo ní ìpínlè Benue kí ó tó di wípé won darapò mó àwon Desmony Nig. Ltd.
Won sisé pèlú àwon Desmony Nigeria Ltd, ilé-isé àwon Italy ní ìgbà kékeré gégé bí olórí àwon awakò kí won to dá ti won sílè.
Kí Elédúà té won sí aféfé rere.

About Awo

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.