Home / Àṣà Oòduà / Ifa Toni Ki Bayi Wipe

Ifa Toni Ki Bayi Wipe

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a san wa o, eledumare yio gbo ohun ebe adura wa o ase.

Ifa toni ki bayi wipe:
Orunmila ni ori a lana kan
Moni ori a lana kan
Oni bi odun bati jo o lori “osàn” lo maa un lana fósàn
Orunmila lori a lana kan
Mo lori a lana kan
Oni bi odun bati jo o lori “òro” lo maa un lana fóro
Orunmila ni ori a lana kan
Moni ori alana kan
Oni bi odun bati jo o lori “obì” lo maa un lana fóbì
Orunmila ni ori afàpádìdì foná lo maa un lana fun afapadidi fona
Moni iwo Orunmila kilode ti o fi nfo bi ede bi eyo?
Orunmila loun ko fo bi ede bi eyo, oni akapo toun loun nbawi wipe ori re yio lana ire gbogbo fun.
Eyin eniyan mi, nje mo gbaladura laaro yi wipe eleda wa yio lana ire gbogbo fun wa lonakona ti a ba ro okan si ati ibiti ako ro okan si, lenu ibiti odun yi ku si ao gbegba ope o aaaseee. (OTURA ORILANA).
ABORU ABOYE OOO.

 

 

 English Version:

Good morning my people, how was your night? Hope it was great, may God answering our prayers today amen.
Today’s Ifa said:
Orunmila said head will make path
I said head will make path
He said when the season is at hand a head of “osàn” will make path for osàn
Orunmila said head will make path
I said head will make path
He said when the season is at hand a head of “òro” will make path for òro
Orunmila also said head will make path
I said head will make path
He said when the season is at hand a head of “obì” will make path for obì
Orunmila said it is the head of fire carrier that you to make path for fire carrier
I said Orunmila why are you speaking in parable?
Orunmila replied that he didn’t spoke in parable
Rather to his diviner that his/her head will make a good path for him/her today.
My people, I pray that your head will make a good path for you in all your expectations today, for the remaining of this year you will have a good testimony amen.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...