Home / Àṣà Oòduà / Iwure Ori

Iwure Ori

Orí mi, gbe mi o! (My Orí, support me)
Ori lo da mi (Ori is my Creator)
Eniyan ko o (It is not man)
Olodumare ni (It is Olodumare)
Ori lo da mi (Ori is my Creator)

Ori Onise (Ori, the competent Creator)
Apere Atete gbeni ju Orisa (He who is faster in aiding one than the Orisa)
Ori atete niran( He who instantly remembers his devotee)
Ori lokun (Ori is valuable)
Ori nide (Ori is jewelry)
Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni (No Orisa can favour one without the consent of one’s Ori)
Ori ni seni ta a fi dade owo (It is Ori that aids one for one to be crowned of money)
Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja (It is Ori that bless one for one to be using beaded walking stick even to the market)
Ori ni seni ta a fi lo mosaaji aso oba (It is Ori that bless one for one to be using valuable cloths)
Ori gbe mi (Ori, please, support me)
Ori la mi (Ori, please, bless me)
Ori ma pada leyin mi (Ori, please, never turn against me)
Ase

About fijabi

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Iwulo Ati Anfaani Ti Orí Nse Ninu Igbesi Ayé Omo Eda Eniyan

Ekaaro eyin eniyan mi, aku ise ana o, a sin tun ku imura toni, mose ni iwure laaro yi wipe Eledumare ninu aanu re koni jeki ire oni yi fiwa sile Àse. Idanileko mi toni da lori orí wa, opolopo ni ko mo iwulo ati anfaani ti orí nse ninu igbesi ayé omo eda eniyan, orí je pataki ninu gbogbo eya ara, koda mo fe le sope orí ni gbogbo nkan ile ayé yi, kosi nkankan ti a le se ...