Home / Àṣà Oòduà / Ebami Dasi Oroyii, aare orile ede Naijiria yii Muhamedu buhari…

Ebami Dasi Oroyii, aare orile ede Naijiria yii Muhamedu buhari…

eku ojumo gbogbo awa omo yoruba rere asikoyi atuwa lara ooooo Ase, ebami dasi oroyii, aare orile ede naijiria yii muhammedu buhari ti yowo yose kuro lori oro epo, epo tiwa di N145 per littre, sugbon eje karantipe nigbati ijoba ana fe yowo kuro lori subsidy tinubu, atiku abubakar, fashola, pariwo pe ki jonathan mase be nitori awon omo naija majiya, nigbati eto idibo de egbe APC gbagboro kankan pelu ariwo say buhari say baba awa omo naija na ao si fimu finle akon debo wa fun egbe APC niyen laimope ete lama babo nibe, nisin amabere sini ra epo ni N145, ejo igbawo lamaseida nitori inira yii po.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Buhari kí Obaseki kú oríire

Buhari kí Obaseki kú oríire Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ránṣẹ́ kú orííre sí Godwin Obaseki lẹ́yìn tó jáwé olúborí nínú ìdìbò gómìnà tó wáye lónìí nípìnlẹ̀ Edo. Obaseki tó jẹ́ olùdíje dupò gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ló fi ìdí akẹgbẹ́ rẹ̀ lábẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú APC Ize-Iyamu janlẹ̀. Nínú àtẹjáde náà ti Garba Shehu tó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ pàtàkì fún Ààrẹ Buhari lórí ìpolongo fọwọ́sí, ló ti dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn elétò ìdìbò fún bi wọ́n ṣe kéde Obaseki bí ẹni to ...