Buhari kí Obaseki kú oríire Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ránṣẹ́ kú orííre sí Godwin Obaseki lẹ́yìn tó jáwé olúborí nínú ìdìbò gómìnà tó wáye lónìí nípìnlẹ̀ Edo. Obaseki tó jẹ́ olùdíje dupò gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ló fi ìdí ...
Read More »Ìjọba Nàìjíríà kéde ìlànà tuntun fún ìséde Kofi-19
Ìjọba Nàìjíríà kéde ìlànà tuntun fún ìséde Kofi-19 Ṣe àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní kò sí ohun kan tó le le le tí kìí padà rọ̀, ìdí nìyí tó fí jẹ́ pé, ìrọ́jú ló yẹ ẹni tí eégún bá ń ...
Read More »Ìṣẹ parí fún òṣìṣẹ́ tó bá gbé àṣírí Ìjọba jáde lọ́nà àìtọ́—Ìjọba àpapọ̀
Ìṣẹ parí fún òṣìṣẹ́ tó bá gbé àṣírí Ìjọba jáde lọ́nà àìtọ́—Ìjọba àpapọ̀ Ṣé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, ìlú tí kò sófin, ẹ̀sẹ̀ kò sí níbẹ̀, gẹ́lẹ́ bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ Orílẹ̀ yìí dà báyìí, bí Ìjọba àpapọ̀ se ni ...
Read More »Ààrẹ Buhari dijú lé Ọ̀gá Àjọ NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn tó jàjẹbánu
Ààrẹ Buhari dijú lé Ọ̀gá Àjọ NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn tó jàjẹbánu Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti fi ọwọ́ òṣì júwe ilé fún adarí àjọ elétò ìdánwò àṣekágbá ti girama, NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn lórí ẹ̀sùn pé ...
Read More »Ẹlẹ́wọ̀n 2600 ni ìjọba tú sílẹ̀ ní Nàìjíríà nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus
Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tú ẹlẹ́wọ́n tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì sílẹ̀ ní ọgbà ẹ̀wọ̀n káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Aregbesọla ní Ìjọba gbé ìgbésẹ̀ náà láti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn Coronavirus ní Nàìjíríà. Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà ni àwọn ...
Read More »Foto: Baba ati omo
O wu Olodumare lo da erin ni ola, Olodumare loni ko ri be.
Read More »Ebami Dasi Oroyii, aare orile ede Naijiria yii Muhamedu buhari…
eku ojumo gbogbo awa omo yoruba rere asikoyi atuwa lara ooooo Ase, ebami dasi oroyii, aare orile ede naijiria yii muhammedu buhari ti yowo yose kuro lori oro epo, epo tiwa di N145 per littre, sugbon eje karantipe nigbati ijoba ana ...
Read More »Aare Buhari pe eni odun metalelaadorin (73) lonii
Igba odun, odun kan ni
Read More »“Oruko awon to ja Naijiria lole ko ni pe jade” – Buhari
Aare Buhari ti fi da awon omo Naijiria loju wi pe, laipe, awon oruko awon ojelu ti won ko owo Naijiria je ko ni pe di tite jade fun gbogbo aye. Gege bi oro re, eleyii to se nibi ipade ...
Read More »Enikan ti Buhari gbagbe lati fun ni ipo misita
Ohun ti Ogbeni Yanju Adegboyega ko nipa maanu naa ni yii: “Walaaahi! Mo sese gbagbo loooto ni pe, alaimoore lo po julo ninu awon oloselu. Olorun n gbo, alaimoore ni Aare Buhari ati egbe oselu APC. Eyin o gbagbo? O ...
Read More »