Home / Àṣà Oòduà / Okò tí ó gbé epo petiírólù àti okò èrò ni ó kolu ara won ní Orlu Imo, ogbòn èèyàn ni ó kú.

Okò tí ó gbé epo petiírólù àti okò èrò ni ó kolu ara won ní Orlu Imo, ogbòn èèyàn ni ó kú.

Ìjàmbá nlá ni ó selè ní orí afárá (bridge) tí ó gbajúgbajà ní Njaba lónà Umuaka – Okwudor ní ìpínlè Imo. Gégé bí ìròyìn se so okò epo petiírólù àti ti gáàsì tí ó kolu bóòsì elérò méjìdínlógún ní Orlu, won sì gniná lésèkesè tí ó sì pa èèyàn ogbòn(30).

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.