Home / Àṣà Oòduà / Oríkì Fún Ọba

Oríkì Fún Ọba

Kábíyèsí Ọba Olúwayé,
Ọ̀dúndún aṣọ̀’de d’ẹ̀rọ̀,
Ọba adé-kí-ilé-r’ójú
Ọba ade-kí-ọ̀nà-rọrùn,
Arówólò bí òyìnbó,
Ó fi’lé wu ni,
O f’ọ̀nà wu ni.
Ògbìgbà tí n gba ará àdúgbò
Ọba at’áyé-rọ bí agogo.

Olubadan

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Olubadan

Awon omo Alade yari: Yoruba fe gba’ra re lowo ajeji Fulani to n tele basubasu

Akeredolu yari kanle. Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe… . Akeredolu yari kanle. Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe. Gani Adams n yona lenu lori laasigbo Wakili. Sunday Igboho si gegun kale Igbaniloju naa ti n lo, ojo pe die, sugbon bayii, o jo pe ile Yoruba ti setan ati gba ara re kale lowo ajeji godogba to n te’le basubasu.Awon atilaawi yii gan-an ni awon Fulani, paapaa awon darandaran, ...