Home / Àṣà Oòduà / Ota ìbon tí àwon olópàá àti àwon ìgárá olóshà n yìn mó ara won sè sì bá awa kèké kan ní ìpínlè River.

Ota ìbon tí àwon olópàá àti àwon ìgárá olóshà n yìn mó ara won sè sì bá awa kèké kan ní ìpínlè River.

    Oní kèké kan ní PortHarcourt ni ó ti kú látàrí ota ìbon tí ó se sì ta ba nígbà tí àwon ìgárá olóshà àti olópàá n yin ìbon mó ara won.

Òdókùnrin tí ó jé oní kèké yí tí ó wá láti ìpínlè Ebonyi ti kú ikú òjijì nígbà tí ìbon ta ba léyìn tí ó jeun tán ní ilé oúnje .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.