Wizkid pa Davido, Techno àti àwon míràn tí ó wá fún àmì èye AFRIMA ti odún yí láyò. Wizkid gba èbùn fún orin rè ” Come closer ” tí ó ko pèlú Drake.
Home / Àṣà Oòduà / Wizkid ni ó gbé igbá orókè gégé bi okùnrin àkókó ní bi àmì èye AFRIMA ti odún yí ó sì pa Davido láyò.
		
		
		
		Tagged with: Àṣà Yorùbá
 Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
				
