Home / Tag Archives: iroyin (page 6)

Tag Archives: iroyin

Nítorí Àrùn Coronavirus Ìjọba Àpapọ̀ Ní Káwọn Arìnrìnàjò Láti Orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà, Gẹ̀ẹ́sì, Faransé Àtorilẹ̀èdè Mọ́kànlá Míràn O Gbélé Wọn

Bákan náà ni Ìjọba àpapọ̀ tún ṣàlàyé pé àṣẹ yìí ló bẹ̀rẹ̀ sí ní fi ẹsẹ̀ múlẹ̀, bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ Sátidé, ọjọ́ kọkànlélọ́gún oṣù kẹta ọdún 2020.

Read More »

Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩

Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩– Iroyin lati Owo Akinwale Taophic. Latari iku odo agbaboolu, Chineme Martin’s, eni ti o pade iku ojiji ni abala akoko ifigagbaga ose ketalelogun liigi orileede wa Nigeria, NPFL, ti o waye laarin Nasarawa United ...

Read More »

Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn wọ́gilé ìyọnípò Oshiomole gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC

Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn wọ́gilé ìyọnípò Oshiomole gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC

Read More »

Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn

Arabinrin ti o sese ti ilu London de ni o bere si nii wuko ti o si n se kata. Ni eyi ti o mu ki o fara re sile fun ayewo coronavirus.

Read More »

Ọ̀nà Jìbìtì

Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa ti a maa n gbe moto lo si ibi inawo.

Read More »

Ọba mẹ́wàá, ìgbà mẹ́wàá

Awon onpitan wu itan Emir Kano ana jade. Won ni oro re dabi egun ti baba baba re ti se sile. Won ni odun 1963 ni ede aiyede waye laare Emir Mohammed Sanusi to je baba eni ti gomina yo ...

Read More »

Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn

Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn Ọjọ́ kẹjọ ọdọọdún ni àyájọ́ àwọn obìnrin lágbàáyé níbi tí gbogbo àgbáyé tí ń kọjú sí àwọn obìnrin láti yòǹbó àwọn iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n gbé ṣe láì nọ́ọ́ní onírúurú ìpèníjà, ẹ̀dùn ọkàn ...

Read More »

Ènìyàn mó̩kàndínlógójì ti ní àsepò̩ pèlú alárùn coronavirus l’Ogun

Iberu bojo ti po gan-an ni ipinle Ogun bayii, paapaa julo lati igba ti ayewo ti fihan pe alarun buruku kan ti wo orileede yii lati orileede Italy.

Read More »

El- Rufai bá e̩bí ènìyàn 51 ké̩dùn

El- Rufai bá e̩bí ènìyàn 51 ké̩dùnNnkan buruku sele ni ilu Giwa ati Igali ni oru ojo aiku moju ojo Aje.Awon adihamora ni won tun ya bo awon ilu ati abule ni ipinle Kaduna ti won si bere si pa ...

Read More »

Ilé-ẹjọ́ fi mílíọ̀nù mẹ́wàá náírà fa APC létí

Ejo ti ile-ejo giga to fi ikale si ilu Abuja da ni ojo ketala, osu yii ni egbe oselu APC ni awon ko fara mo.

Read More »