Home / Tag Archives: Obj

Tag Archives: Obj

obj

Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19

Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19 Fẹ́mi Akínṣọlá Agbẹnusọ fún Bàbá Ọbásanjọ́, Kehinde Akinyemi ló fi léde bẹ́ẹ̀ nínú àtẹjáde ní Ọjọ́ Ìsinmi pé àyẹ̀wò fihàn pé kò ní àrùn Kòrónáfairọ̀ọ̀sì. Akinyemi ní Ọjọ́ Keje, Oṣù Kẹjọ, ọdún 2020 ...

Read More »

Ọbásanjọ́ tìkẹ̀kùn mọ́ àwọn òṣìṣẹ́, ojúlùmọ̀ níbi òkú àna rẹ̀

Ọbásanjọ́ tìkẹ̀kùn mọ́ àwọn òṣìṣẹ́, ojúlùmọ̀ níbi òkú àna rẹ̀ Ṣé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, bí ìṣẹ̀lẹ̀ bá sẹ̀ ní agboolé, a mọ́ ọ kángun sẹ́nìkan ju ẹnìkan lọ.Ọ̀rọ̀ rí bẹ́ẹ̀, nígbà tí Àárẹ̀ tẹ́lẹ̀rí lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Olusegun Obasanjo ...

Read More »