Home / Àṣà Oòduà / Iwure Ojo Eti

Iwure Ojo Eti

Moki gbogbo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla wayi o
Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.)
(.Ilosiwaju Ishese Lo Jemi Lo Gun o.)
Mofi asikoyi gba ni iwure fun gbogbo eda omo adariwuhun tioba lefi atejishe ee se (Aseee) labee post yi
Oro aseti koni je temi teyin o
Akoni ti o taya tomo toko o
Akoni tee oo
Akoni si ile tee o
Akoni ri ogun atimole o
Osu tiawa bee yi koni nje osu ibanuje funwa o
Osu tiawa bee yi idun nu. Ayo. Alafia. Igbega. Ilosiwaju. Isegun ota. ile kiko. Motor rira. Lomaje fun gbogbo wa lapapo oo
Gbogbo abiyamo
Ekoni fi oju sunkun omo
Ekoni fi oju sunkun aya
Ekoni fi oju sunkun oko
Ekoni fi oju sunkun ara yin o
Letter ayo eni kokan wa koni faya o
Ogun akawo le ori
Ogun afese janle koni je ti eni kokan wa o
Ogun akoba
Ogun adaba
Koni je ti gbogbo wa lapapo oo
(.Emi Ni Tiyin Toto.)
Ojogbon Awo Mimo
Aare Afifadara Kinnihun Orunmila

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Iwure AJE

Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje pe le oa kin lOrisas Agede ni wo Ajenje lotu Ife ti o fi njo koo ti ni Aje dakun wa jo koo temi ki or ma kuro mud my Translation Continue after the page break