Home / Àṣà Oòduà / A o ni jin sofin aye pelu ase Olodumare. Ase o…

A o ni jin sofin aye pelu ase Olodumare. Ase o…

Ofun saa lefun
Ofun saa losun
Ofun saa ni moriwo Ope yeyeye
A difa fun Alagemo terekange
Tii se Omo Orisa igbowuji
Nitori ajeku Baba Alagemo
Nitori amunku Baba Alagemo
Won ni ki Alagemo losi apookun
Kio lo si ilameji Osa
Ki Ooni Okun,
Ooni osa, mu Alagemo sohun
Arale emo jo o
Arale emo yo o
Ooni okun ooni osa
Ti mu Alagemo loni otan moree
Alagemo ni lailai lomo tije ajeku Baba
Lailai lomo ti mu amunku Baba.
Nitori ajeku Baba oun Alagemo
Nitori amunku Baba oun Alagemo
Eni ki oun lo sapa okun
Ilameji osa
Kii ooni okun, ooni osa
O mu oun Alagemo sohun
Arale ema jomo o
Arale emo yo mo o
Ooni okun, Ooni osa
O le mu Alagemo loni
O tan more.
(A o ni jin sofin aye pelu ase Olodumare). Ase o.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Iwure AJE

Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje pe le oa kin lOrisas Agede ni wo Ajenje lotu Ife ti o fi njo koo ti ni Aje dakun wa jo koo temi ki or ma kuro mud my Translation Continue after the page break