Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán Saraki nígbà tí won se ìpàdé pèlú Woke, Ortom àti àwon míràn ni ìpínlè Kwara.

Àwòrán Saraki nígbà tí won se ìpàdé pèlú Woke, Ortom àti àwon míràn ni ìpínlè Kwara.

Àwon ìgbìmò tuntun rè é, Gómìnà ìpínlè River, Nyesom Ezenwo Wike tètè dé sí Ilorin ní ìpínlè Kwara fún ìpàdé pàtàkí náà pèlú àwon ti Benue náà, Gómìnà Samuel Ortom tí ó sèsè ko ìwé láti fi egbé APC sílè fún èyí tí a kò tí mò.
Sineto George Sekibo, Sineto Adawari pepple àti àwon míràn ni ó sin Gómìnà Wike lo sí ibi ìpàdé náà.
Àwon Gómìnà méjèèjì ti se ìpàdé pèlú Sineto Bukola Saraki àti Gómìnà ìpínlè Kwara, Abdul Fatah Ahmed.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo