Home / Àṣà Oòduà / Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode

Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode

Orisun
Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode
*Komisanna lo pase fun awon olopaa

Olayemi Olatilewa

Owo awon olopaa ipinle Ogun ti te awon afura si kan gege bi omo egbe okunkun ni Ijebu-Ode.

Gege bi atejade kan eleyii ti alarinna fun ile ise olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Olumuyiwa Adejobi fi sita. Adejobi so wi pe awon omo egbe okunkun bi ogbon (30) ti won ti n yo alaafia Ijebu-Ode ati agbegbe re lenu ni won ti pada ko sinu pakute awon olopaa kogberegbe ti ile ise awon fon sigboro.

Gege bi alaye re, Adejobi ni aimoye iroyin isele orisiirisii lo ti n kan awon nipa ise buruku ti awon omo egbe okunkun naa n da lara. O ni eyi lo mu ile ise olopaa ipinle Ogun, labe komisanna Valentine Ntomchukwu lati jigiri si isele naa nipa didekun awon onise okunkun naa.

Pupo awon afura si ti owo te naa ni won mu ni opopona Fidipote, abule Ogbogbo, Ita Alapo ati awon ile itura ti awon omo eriwo ti n pade.

 

Orisun

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo