Home / Aarin Buzi / E wo ohun ti Funke Akindele n se lowo?

E wo ohun ti Funke Akindele n se lowo?

Funke Akindele ti pada si ni sere idaraya eleyii to n se lati din ara sisan re ku. Awon obirin onise tiata maa n se eleyii lati mu ara awon wa ni ipo odo, eleyii to se pataki si irufe ise ti won yan laayo.

About BalogunAdesina

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*