Home / Àṣà Oòduà / Ìdí Tí Ó Fà Á Tí Mi Ò Ní Fi Lo Káàdì Ìrántí (Memory Card) Láyémi Mó. 

Ìdí Tí Ó Fà Á Tí Mi Ò Ní Fi Lo Káàdì Ìrántí (Memory Card) Láyémi Mó. 

Ìdí méji pàtàkì tí mi ò fi lo káàdì ìrántí (SD card) mó.
SD card tí a mò sí káàdì ìrántí (memory card) tí a tún mò sí káàdì ìrántí ìtá “external memory “,ní tòótó ó jé ohun tí ó wópò tí àwon omo orílè èdè Nàìjíríà ní, sùgbón tí kò papò mó orílè èdè míràn bí àwon se ń lo ohun ayé tuntun tí a mò sí cloud storage (ìpamó àwosánmò )…
Ó jé wípé… Ó se ni láànú wípé orílè èdè Nàìjíríà jìnà sí lílo irú nkan wònyí, nínú àbájáde yìí máa sàlàyé fún yín ewu tí ó wà nínú lílo káàdì ìrántí (SD card) tí mo sì ní ìgbàgbó wípé okàn yín leè yí láti lo ibi ìpamó míràn bíi ìpamó àwosánmò (cloud storage)
Ní àkókó n bèrè pèlú ewu ìlo káàdì ìrántí( SD card) …
1. Ó máa ń fà àìsùn èro ìbánisòrò …
Njé o ti è ti wòye àbi o ti gbìyànjú láti se àfiwé ìyára tí o bá tan èro ìbánisòrò (phone) re bí? (tí ó túmò sí iye àkókò tí ò ń lò láti tàn  án àti láti pa á?). Tí ó bá sì jé wípé o ti gbìyànjú rè rí, wà sàkíyèsí wípé èro ìbánisòrò re yóò yára tàn láìní káàdì ìrántí (SD card) papàá jùlo àwon tí won ní ìrántí tí ó gbàyè bíi 64,128,256GB…èyí ni ó fa flagship bíi Xiaomi mi6 pèlú èyí tí ó ń bò lónà Essential PH-1 tí won ti gbé sílè láìsí àyè lílo káàdì ìrántí (SD card )…gbogbo atótónu mi ni láti so fún yín wípé káàdì ìrántí (SD card) leè fa àìsùn èro ìbánisòrò (phone) tàbí kí ó dúró sinsin  … E se  sàkíyèsí wípé ó leè jé ohun tí kò ní farahàn nínú àwon èro ìbánisòrò míràn lára àwon tó ní ìlosíwájú àti tó kéyìndé bíi “Snapdragon SOc “tàbí sèsèdé “Mediak Chipsets Series “.
2. Kòkòrò tí ó máa kolu èro ìbánisòrò (Virus attack).
Ní tòótó òpó ènìyàn ló mò nípa òtító tí ó korò yìí… Káàdì ìrántí máa ń fa kí Kòkòrò tètè kolu èro ìbánisòrò kò sí síse kòsí  àìse pí paré ni a ó paáré ó sì le fa kí ènìyàn pa ohun tí ó wúlò ré mo bíi Orin, fídíò, àwòrán Abby. Fún àkókò yí mo lérò wípé mo gbìyànjú láti yí okàn yín padà díè, e jò wó mi ò so wípé kí e ma ra káàdì ìrántí (memory card) mó nkan tí mò ń gbìyànjú láti so ni pé… Ìgbà míràn tí e bá fé gba èro. E lo fún èyí tí ìrántí rè pò tí ó sì dára tí e kò fi ní nílò láti ra káàdì ìrántí (SD card) àti àwon ewu tí ó ba wá….

English version
Continue after the page break.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo