Home / Àṣà Oòduà / Igba otun de ba Majek Fashek: O korin ni Felabration

Igba otun de ba Majek Fashek: O korin ni Felabration


Bi Eledumare  ba ran eda lowo, bi idan ni i ri. Majek Fashek ti opolopo sebi o ti tan fun latari bi okunrin naa se fi ogun oloro baye ara re je, ti ko si ni kobo lowo mo lati fi jeun.  Okunrin olowo kan ninu Warri, Ayiri Emami ni Oba oke ran si i. O fi owo se itoju re, okunrin olorin naa si pada bo si po pada.  Majek Fashek re e nibi o ti n korin nibi ayeye ti won se lati fi bu ola fun oloogbe Fela Kuti, Felabration.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*