Home / Àṣà Oòduà / Iwure Osu Tuntun 01-05-2016

Iwure Osu Tuntun 01-05-2016

E MAA WI TELE MI :
………
*Osu karun-un yii, osu ire owo ni fun mi.
*Osu ire ile kiko ni fun mi.
*Osu ti maa ra oko ayokele.
*Osu igbega lenu ise mi ni.
*Osu idunnu ni yoo je fun ni.
*Osu aseyori mi ni.
*Osu ayo mi ni.
*Emi ni oloriire akoko ninu osu yii(Ase Edumare).
……….
E ku ojulona IBILE FESTIVAL SEASON1 ‪#‎IFS‬.
……….
Ijo ibile.
Ilu ibile.
Orin ibile (Ewi, Ijaala, Esa).
Iwosan ibile.
Ounje ibile.
Aso ibile.
Iwo naa le wa soju ilu re pelu ounje ati nnkan ibile ilu re, nibi ayeye ‪#‎IBILE2016‬.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Iwure AJE

Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje pe le oa kin lOrisas Agede ni wo Ajenje lotu Ife ti o fi njo koo ti ni Aje dakun wa jo koo temi ki or ma kuro mud my Translation Continue after the page break