Home / Àṣà Oòduà / Iwure Osu Tuntun 10/2016

Iwure Osu Tuntun 10/2016

Moki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. Nla wayi oo
Wipe :- (.Kinnihun orunmila .O)
(ilosiwaju ishese lo jemi lo gun o)

(…. Ema wi tele mi wipe ….)
Osu yi asan mi sowo
Asan mi saje
Asan mi sayo
Asan mi somo
Asan mi saiku
Asan mi si idun nu
Asan mi salafia
Asan mi si ire gbogbo oo
Gbogbo adawole mi ayori si rere oo
Gbogbo agbekele mi koni jasi ofo oo
Gbogbo ibiti moro kan ore si mari ore gba nibee o
Gbogbo ibi timio rokan ore si mari ore nla gba nibee o
Madi eni apesin oo
Erin ayo ni yioma gba enu mi jade o
Akoba adaba koni je temi o
Iku ojiji koni je temi taya tomo o
Gbogbo ohun rere timo dawo mi le losu to koja ti ko yori
Lashee edumare ayori si rere ninu osu kewa yi ooo
Beni yiori oo
Lagbara lowo olodumare
Nipa ashee enu irunmole igbamole
Lola titobi oruko ati ipo ojishe nla julo orunmila (a.T.S.) niwaju olodumare
Asheeeeeeeeeee beeeeeeeeee
(….Emi ni ti yin toto….)
Ojogbon awo mimo
Afifadara kinnihun orunmila

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*