Home / Àṣà Oòduà / Iwure Owuro – 05.07.2016

Iwure Owuro – 05.07.2016

E MAA WI TELE MI :
……..
*Edumare ma se je ki n fi ota s’ore.
*Oluwa gba mi lowo afoju-feni ma fokan-feni.
*Edumare gbe mi leke abinu eni.
*Oluwa ma se je ki n je egungun kehin eran.
*Edumare ma se je ki n subu fun ota yo(Ase).
Q

E KU OJULONA ‪#‎IBILE_FESTIVAL_SEASON1‬.
……….
Ilu ibile.
Ijo ibile.
Orin ibile (Ewi, Ijaala, Esa).
Iwosan ibile.
Ounje ibile.
Aso ibile.
‪#‎IBILE2016‬
……..
Fun ekunrere alaye : +2347031174331.
+2347062422360.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Iwure AJE

Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje pe le oa kin lOrisas Agede ni wo Ajenje lotu Ife ti o fi njo koo ti ni Aje dakun wa jo koo temi ki or ma kuro mud my Translation Continue after the page break