Home / Àṣà Oòduà / Odún dé, ore yèyé òsun.

Odún dé, ore yèyé òsun.

Òsun Osogbo tún ti dé lónìí tí se ojó ketaàdínlógún osù kejo odún, 2018, tí gbogbo àgbàyé fi n se odún fún Òsun éléyinjú àánú, igbómolè obìnrin

Òsàyòmolè
Nílé ìyà olúgbón won kò gbodò mawo
Ìran arèsè kò gbodò morò
Olúwa mi ló morò lósì mopa
Òsun lo mopa tééré tí í pa won jé…

Ore yèyé òsun oooo
A kí yín kú odún lénìí, àsèyí se àmódún àse àmódún se èmíì.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo