Home / Àṣà Oòduà / Èèmò lukutu pébé ní ilé-èkó gíga ìfáfitì ti Ilé-ifè : Nígbà tí akékòó kan ya wèrè nígbà tí ó n kàwé lówó.

Èèmò lukutu pébé ní ilé-èkó gíga ìfáfitì ti Ilé-ifè : Nígbà tí akékòó kan ya wèrè nígbà tí ó n kàwé lówó.

Gégé bí a ti mo wípé òkan gbógì ní ilé-èkó gíga Òbafemi Awolowo University (OAU) jé ní orílè èdè Nìjíríà yí.

Sà déédéé ni a gbó wípé arábìnrin kan tí ó jé akékòó ilé-èkó yí ya wèrè látàrí ìwé kíkà nígbá yí ó jé wípé ìdánwò won ti kù sí dèdè.

Ní alé ìjeta ni ìsèlè yí selè, nígbá tí omobìnrin yí sa wèrè tán, ìwé tí ó n kà náà ló fi ñ lu ìlù. Àfi kí elédùà gbàwá ooo.

 

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo