Home / Àṣà Oòduà / Odu Ifa Owonrin Obara – Faniyi David Osagbami

Odu Ifa Owonrin Obara – Faniyi David Osagbami

| | |
| | | |
| | |
| | |

 

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si ku isimi opin ose, mo gbaladura laaro yi wipe ako ni pejopo sunkun ara wa o ase.
Odu ifa OWONRIN OBARA lo gate laaro yi, odu ifa yi gba eniti o ba jade si niyanju wipe ki o se etutu daradara nitori ki o ba le bori iku ojiji, aisan, ofo, ibanuje ati gbogbo ajogun ibi patapata.
Ifa naa ki bayi wipe: Owonrin barabara a difa fun olofin lojo ti iku nfile re nkan firii, aisan, ofo, ejo, ibanuje ati gbogbo ajogun ibi nfile re nkan firii won ni ko karale ebo ni ki o se nitori ko ba le bori gbogbo won, ki ofo ma baa sele ninu idile re, obi meji, eru eko, eru akara, apata okete, eyin adiye 9, epo pupa, iyo ati igba ewe ayajo ifa, olofin kabomora o rubo won si se sise ifa fun, lati igba naa ni olofin ti segun iku ojiji ati gbogbo ajogun ibi patapata, olofin wa njo o nyo o nyin awo awon awo nyin ifa, ifa nyin eledumare oni nje riru ebo a maa gbeni eru arukesu a maa da ladaju nje ko pe ko jina ifa wa bami larusegun arusegun ni a nba awo lese obarisa.
Eyin eniyan mi, mo gbaladura laaro yi wipe iku ojiji koni pawa tidile tidile, aisan, ofo, ejo, ibanuje ati gbogbo ajogun ibi koni je ipin tiwa, ako ni sunkun lori ara wa loni, bi a se njade lo loni oju aanu eledumare yio wa pelu wa, won kosi ni le kalenda obutuari wa lasale o aaaseee.
ABORU ABOYE OOO.

 

English Version:

Good morning my people, how was your night? Hope it was great, wishing you all happy weekend, I pray this morning that we shall never mourn over ourselves ase.
It is OWONRIN OBARA corpus that revealed this morning, ifa advised whoever this corpus revealed out for that he/she should offer sacrifice in order to avoid the occurrence of sudden death, chronic sickness, tribulations and all sort of evils plan.
Hear what the Corpus said: Owonrin barabara cast divined for olofin(a king) when death, sickness, tribulation, calamity, sorrow, and other evils agents were roaming about around his house he was advised to offer sacrifice so that no evil may befall or enter his house, two kola nuts, rat, corncake, cake beans, local eggs 9, palm oil, salt and ifa leaves, and olofin complied with the sacrifice also ifa medicine was prepared for him and he conquered all those agents of evil, he started dancing and rejoicing praising priest the priests were praising ifa while ifa was praising God.
My people, I pray this morning that a sudden death, sickness, tribulation, calamity, sorrow and other agents of evil will never be our portions, we shall never mourn over ourselves, our going out today will never result in pasting out of our obituary calendar ase.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...