Home / Àṣà Oòduà / Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016

Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016

Hummmmmm ile eni lati nje ekute oni dodo,
Morojo oko re feni kankan mo
Tori
Kosi bi tise o si oni kaluku naa nfaso bo tie ni wara o si loni, wara nbo lola

Woo Orewa
Kosokunrin tope nile aiye kaluku naa ngba kadara tie bee ni o
Wa Gbomi Dada
majeki enikan tio pa,majeki won da ile yin ru mo o lowo atipe gbongbon kan o si eyan nio mo tira e
Nje
o mo pe #obinrin ti o ba fi owo arare keru kuro nile oko Eegun buruku lo nfi lele yen fawon omore lojo iwaju
Kini Kan
ni mofe komo daju saka wipe okunrin gidi towa nta koto nkan mo, amo Iwo ti o ba ri tie mu nise ni kodimu sinsin matoripe kosowo lowo re loni kowa fisile oooo… Ile wa oni daru ooo ooo ire oooo

 

K- King Ogulutu Oro

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo