Home / Àṣà Oòduà / Onka ede Yoruba 100 – 20,000

Onka ede Yoruba 100 – 20,000

210- Ẹwalerugba
220- Ogunlugba
230- Ọgbọnwolerugba
240- Ojulugba
250-Aadọtalerugba
260-Ọtalerugba
270- Aadọrinlerugba
280- Orinlugba
290- Aadọrunlerugba300-Ọdunrun
400-Irinwo, irinwó tabi Erinwo
500-Ẹdẹgbẹta, ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta
600-Ẹgbẹta, ẹgbẹ̀ta
700-Ẹdẹgbẹrin, ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin
800-Ẹgbẹrin, ẹgbẹ̀rin
900-Ẹdẹgbẹrun, ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún
E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow)

About BalogunAdesina

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo