Home / Àṣà Oòduà / #Opele- Ifa ni…

#Opele- Ifa ni…

Ifa ni:
Opele lo yo tan lo dakun de’le
A difa fun peregede tii se Yeye Ojumomo. Ojumo to mo wa loni ojumo ire ni Peregede!
Ifa iwo ni Yeye Ojumomo
Ojumo to mo wa loni ojumo Ajé ni Peregede
Ifa iwo ni Yeye Ojumomo
Ojumo to mo wa loni ojumo alafia ni Peregede
Ifa iwo ni Yeye Ojumomo
Ojumo to mo wa loni ojumo ayo ni Peregede
ifa iwo ni Yeye ojumo mo!
Aase!

 

Idowu Odeyemi

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*