Home / Àṣà Oòduà / ORIKI ORILE IREMOGUN

ORIKI ORILE IREMOGUN

oriki
Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni.Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ro baba.Omo bibi onire ni i remu sekele.Omo rowo-rowo-rowo.Balagbede o ba rowo.Toloko taladaa.Won a maa so lona oko.Ki lo mu ki won maa so lona oko?Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi

About oodua

One comment

  1. Ismail Abdus-Salam

    A dúpẹ́ púpọ̀ fun oríkì orílẹ̀ Ìrèmògún yìí. Ṣùgbọn kò rọrùn púpọ̀ láti kà nítorí àìní ̀àmìn ohùn lókè àti nísàlẹ̀. Ẹ jọ̀wọ́ é bá wa se àtúnkọ rẹ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Oríkì Fún Ọba

Kábíyèsí Ọba Olúwayé, Ọ̀dúndún aṣọ̀’de d’ẹ̀rọ̀, Ọba adé-kí-ilé-r’ójú Ọba ade-kí-ọ̀nà-rọrùn, Arówólò bí òyìnbó, Ó fi’lé wu ni, O f’ọ̀nà wu ni. Ògbìgbà tí n gba ará àdúgbò Ọba at’áyé-rọ bí agogo.