Home / Àṣà Oòduà / Orile ede, Russia, Iraq ati Syria, Fa oju ro si orile-ede Amerika.

Orile ede, Russia, Iraq ati Syria, Fa oju ro si orile-ede Amerika.

Ijoba ile America ti se igbekale dosinni ti (Tomahawk) oko ohun ija ofurufu ni Siria, eyi ti awon kan ti oruko won un je
(Pentagon) mo nipa re ni Ọjọbọ
Ni ibamu si osise, (Washington) so wipe kemikali ija ikolu ti o sele ni ojo isegun, je ti oun ti won gbekale lati (Air-field) ni
orile-ede Amẹrika.

 

‘Sugbon, minisita ile okere ni ile (Russian) so wipe ikolu ti ile Amerika kolu Siria tumo si wipe Amerika fe ki Siria ati awon  orile-ede ti o ku ma beru won ni, ati pe ikolu na je.’
‘Nigba ti ati mo tele wipe awon kan ti a un pe ni (OPCW) so ni odun ti o koja (2016), wipe Siria ko ni oun ija iyẹfun oloro ni ipamo mo.’

 

‘ Eniyan kan ni ile igbimo asofin kan ni ile (Russian) ti orukore unje Igor Morozov, so wipe akolu na ki se akoko lati orilede-ede Amerika, si orile-ede miran, li tori wipe, bi ile Amerika se ju ado oloro yi si orilede-ede (Yugoslavia, Iraq, Libya) ati awon orile-ede miran lati pawon run, ni eyi ti  ile Amerika ti se tapa si ofin, ile okeere.’
Ogbeni Morozov, so fun ile ise ero aye lujara kan wipe isele na ti di eri wipe awọn kemikali ikolu ni (Idlib) wà lati ile America.

Aare Orile-ede ile (Russian) ogbeni (Putin) so wipe ikolu ile Amerika si ile Siria bi ohun ninu de bi wipe eyi se afihan wipe notito ni Amerika ti tapa si ofin gbogbo agbaye ti won jo se.
Nipase eyi, ijoba orile-ede (Russia) ti si ikọsilẹ ibajose pẹlu orile-ede ile Amerika ati Siria ni pa abo.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo