Home / Àṣà Oòduà / Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.
Olùsó Daniel Udoh, tí ó dá ilé ìjosìn “Agbejórò ni jésù” sílè ni owó sìkún ìjoba ti tè ní Akapabuyo, ìpínlè Cross river látàrí fífi tipátipá bá omo rè obìnrin odú méje lòpò.
Udoh ni won ti fi sèsín káàkiri pèlú àwon mókàndínlógórin(79) elésè míràn ní Calabar.
Omo rè wà ní ilé-ìwòsàn tí ó n gba ìtójú lówó fún ìjàmbá tí ó selè si.

About Awo

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára